Chapter 1 Flashcards
(55 cards)
1
Q
corn
A
àgbàdo
2
Q
Clothes
A
aṣọ
3
Q
Father
A
bàbá
i.e mi o jọ baba mi rara
4
Q
Ball
A
bọ́ọ̀lù
5
Q
to play
A
eré
6
Q
palm wine
A
ẹmu
7
Q
ẹyin
A
egg
I.e mo ni ẹyin mẹta
8
Q
ilé
A
House
mo ni ilé maarun
9
Q
ìrẹsì
A
rice
Mi o fẹ́ ìrẹsì, mo fẹ́ moinmoin
10
Q
Sir
A
Ọ̀gbẹ́ni
11
Q
Teacher
A
olùkọ́
12
Q
Name
A
orúkọ
I.e kí lorúkọ ẹ?/ kí lorúkọ rẹ/ yín (form.)
13
Q
owó
A
money
I.e mo fẹ́ owó
14
Q
stew
A
ọbẹ̀
15
Q
Watch
A
aagoo yín (rẹ. info)
16
Q
thank you
A
a dúpẹ́
17
Q
asọọ̀ rẹ
A
your clothes
18
Q
iléè rẹ̀
A
his/her house
19
Q
their money
A
owó wọn
20
Q
birthday
A
ọjọ́ ìbí
21
Q
our car
A
Mọ́to wa
22
Q
ẹpa
A
mi o kí n jẹ ẹpa (kí n -never-continuous thing)
23
Q
gbá
A
to kick
24
Q
fẹ́
A
to want
I.e Ewo lo fẹ́ ninu Apple phone, Samsung ati Google?
25
gbé
to live
I.e nibo lò n gbé? Mò ń gbé ni…
26
jẹun
to eat
I.e mo ti jẹun ìrẹsì
27
i like to (hobby)
Mo fẹ́ràn láti…
I.e mo fẹ́ràn lati kàwé
28
mu
to drink
i.e mi o mu ẹmu
29
how are things/you?
báwo ni?
30
ṣúgbọ́n
but
i.e mo fẹ́ràn láti ṣeré ìdárayá ṣugbọ́n, mi o fẹ́ràn láti ṣe cardio
31
tàbí
Or
ṣe ẹ fẹ́ jẹ ìrẹsì tábì iṣu? (Yam)
32
Ki lẹ maa wọ?
What will you wear? Mo maa wọ…
33
Ṣàlàáfíà ni?
Àlàáfíà ni tàbí mo wà daadaa adúpẹ́
34
ṣé wà á jókòó?
do you want to sit?
35
ṣé nǹkan ǹ lọ?
Are things going well?
36
Im a little tired
Ó rẹ̀ mí díẹ̀
37
Ẹ káàárọ̀ o
good morning
12:01 - 11:59pm
38
Ẹkáàsán
good afternoon
noon - 5pm
39
Ẹkúùrọ̀lẹ́
good evening
5pm - 7 pm
40
Ẹkáalẹ́
good evening
7pm - 12
41
12-4am
Òru - not usually greeted at this time as peole are sleeping
42
did you rest well?
Ṣé ẹ sinmi daadaa?
43
kú òtútù
greeting for when its cold
44
Kú òjò
greeting for rainy season
45
Kúuṣẹ́
well done
46
happy new year
Ẹ kú ọdún kérésì
Ẹ kú ọdún (general greeting)
47
Ẹ káàbọ̀
welcome
48
Ẹ kú ọjọ́ mẹ́ta o response?
ọjọ́ kan pẹ̀lú tabí awa nìyen o
49
greeting someone you meet at home
Ẹ kúulé
50
And you too?
Ìwọ náà ńkọ́?
51
obí
parents
I.e Bá mi kí àwọn òbí rẹ
52
gbogbo ilé ńkọ́?
how is everyone at home?
53
Is … home?
Ṣè bàbá wà nilé?
wọn ti jáde
54
Kí lorúkọ mama rẹ̀?
Orúkọ́ mama mi ni ….
55
Kú ọyẹ́
harmattan season (november to March - very dry and dusty)