Ogun jija Nile yoruba Flashcards
(2 cards)
1
Q
Awon ohun elo Ogun jija: ibon, Ada, Ida, kumo, esin, ofa abbl.
A
Awon Oogun fun Ogun jija:
Egbe, afeeri, ayeta, afeta, isiju, ariran abbl
2
Q
Awon Ohun ti a fi ndena Ogun jija: Yara, ogba, ifikunlukun, alore, abbl.
A
Awon Ohun ti o maa n fa Ogun jija:
Ija ala Ile,
Ile, ilara, ija fun igi owo, ote, abbl