Pronouns + question words Flashcards
(52 cards)
1
Q
my
A
mi
2
Q
your (singular)/its
A
rẹ̀/ ẹ̀
3
Q
his/ hers/ its
A
rẹ̀/ ẹ̀/ oun/tire
4
Q
yours (plural)
A
yín
5
Q
theirs
A
wọn
6
Q
i
A
eni/mo
7
Q
you
A
iwo/o
8
Q
he
A
oun/abakunrin_ na
9
Q
she
A
oun/ababirin_na
10
Q
we/us
A
awa/ a
11
Q
them
A
awon/won
12
Q
they are fine
A
won wa pa/daada
13
Q
he/she is fine
A
arakunrin(na) wa pa
14
Q
you are fine
A
o wa pa
15
Q
we are fine
A
a wa pa
16
Q
my
A
Mi
17
Q
mine
A
t’emi
18
Q
our
A
tiwa
19
Q
whichever
A
eyikeyi
20
Q
that
A
iyen
21
Q
who
A
tani
22
Q
anyone
A
ẹnikẹni
23
Q
whose .. is this
A
… tani ni eyi
24
Q
myself
A
funrarami/ ara mi
25
himself/herself/itself
funrararẹ̀
26
yourself (normal)
funrararẹ́
27
themselves
funrarawon/ ara won
28
yourself (elder)
funrarayin ara rẹ̀
29
ourselves
awa funra wa/funrarawa/ ara wa
30
i have
mo ni
31
i am
emi ni/ mo je
32
they have
wọn ni
33
they are
wọn je
34
she has/he has/you have
o ni
35
We have
a ni
36
where do you want to go?
nibo ni o fe lati lo?
37
where are we going?
nibo la n lo?
38
we are going to the cinema
a n lo sinima
39
where do you work?
nibo lo ti n sise?
40
where do you live?
nibo lo n gbe/ nibo ni ile e wa
41
im going to see my friends later
mo nlo ri awon ore mi la le yi
42
im going to party
mo lo si Àríyá
43
What time do you want to sleep
Ago melo lo fe sun/ nigba wo lo fe sun
44
I want to sleep at 8 o clock
Mo fe sun ni ago ejo
45
what do you want to eat (young)
ki lo wu e je
46
what do you want to eat (older/ plural)
ki lo wu yin je
47
what do you do at work?
ki lo n se sibise
48
what did you say?
kini nkan to so?
49
Are you coming early next week?
Se o ma wa lose to nbo?
50
how would i pay?
bawo ni maa ṣe san owo?
51
how many?
melo ni?
52
how much?
elo ni?