Adverbs Flashcards
(36 cards)
Lè - Mo lè wá lónìí
Can, may, be able - I can come today
Gbọ́dọ̀ - Mo gbọ́dọ̀ jẹun
Must - I must eat
Sì, dẹ̀
Mo jẹun, mo sì sùn
Mo jẹun, mo dẹ sùn
And - I ate and I slept
Máà - Ẹ máà bínú
Short form - Má
Má sùn
Do not - Do not be angry
Do not sleep
Tètè - Mo tètè lọ
Quickly, without delay - I went quickly
Mọ̀ọ́mọ̀, dìídì
Ó dìídì pè mí
Ó mọ̀ọ́mọ̀ pè mi
Intentionally, knowingly, purposely - He intentionally called me
Ṣì, pàpà
Ò ṣì ń purọ́
Ó pàpà wá
Still - He is still lying
He still came
Kúkú - Ó kúkú gbọ́ bí mo ṣe ń kan ilẹ̀kùn
Indeed, anyway - She indeed heard me knocking
Ṣẹ̀ṣẹ̀ - Mo ṣẹ̀ṣẹ̀ jí
Just now, just this minute - I just woke up
Mà - Ó mà wá lánàá
Indeed, in fact - He indeed came
Tiẹ̀
Ó tiẹ̀ pè mí lòníì
Even - He even called me today
Tún, túbọ̀
Ó tún padà wá lónìí
Again - He came back again today
Ṣáà - Ó ṣáà ti gbọ́
Anyway - He had already heard anyway
Dédé - Ó dédé pè mí lánàá
Suddenly, without reason
She suddenly called me yesterday.
Jàjà - Ó jàjà pè mí láààrọ̀, ò tún ń purọ́
At last, finally - He called me in the morning at last and he was lying again.
Jọ, dijọ̀, jùmọ̀ - A ma dìjọ lọ sí ọjà
A ma jọ lọ sí ọjà
Together - We will go to the market together
Nìkan - Ojo ni ó nìkan jẹun
Alone, single-handed - Ojo ate alone.
As a qualifier - Ojo nìkan ni ó jẹun. It qualifies the noun (Ojo).
Kọ́, kọ́kọ́ - Èmi ni mo kọ́kọ́ dé
Èmi ni mo kọ́ dé
First - I arrived first
Jẹ́ - O ò jẹ́ sùn
Had better not do something - You had better not sleep.
Kàn - Ó kàn pè mi lẹ́ẹ̀kan
Just, simply - He just called me once
Sábà - Ó má ń sábà lọ sí ilé bàbá ẹ̀
Usually - He usually goes to his father’s house
Ò - Mi ò jẹun (ongoing, continuous, habitual)
Mi ò sùn (past)
Not (Negations) - Mi ò gbọ́
I am not eating (ongoing, continuous, habitual)
I didn’t sleep - Past
Ti - Ó ti Èkó dé ní àná
from a place - He came back from Lagos yesterday
Bá - Ó bá bàbá lọ sí ọjà
Ẹ bá mi wá owó mi
for, in company with, on behalf of - He went to the market with father
Search for the money on my behalf