Nouns Flashcards
(100 cards)
Ìpari - Mi ò fẹ́ràn ìparí eré tí mo wò lánàá
End - I don’t like the end of the movie I watched yesterday
Òpin - Ẹ fi òpin sí ọ̀rọ̀ tí ẹ̀ ń sọ
End - End the conversation
Ìsìnmi - Mo fẹ́ràn ìsinmi ní òpin ọ̀sẹ̀
Rest - I like rest during the weekend
Ìsìnkú - Wọ́n ṣe ìsìnkú màmá wọn lánàá
Burial/funeral -They held their mother’s funeral yesterday
Ìtìjú - Wọn ò ní ìtìjú
Shy - She is not shy
Òkú - Wọ́n ma sin òkú ní ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀
Deceased - They will bury the deceased next week
Ìran - Ìran Yorùbá fẹ́ràn òge
Race - The Yorùbá race love fashion
Iṣẹ́ - Mo fẹ́ràn iṣẹ́ mi
Job/work - I love my job
Òṣìṣẹ́ - Wọ́n gba òṣìṣẹ́ tuntun
Worker - She employed a new worker
Ènìyàn - Ènìyàn rere ò wọ́pọ̀
People - Good people are not common
Ayẹyẹ - Mo lọ sí ayẹyẹ lálẹ́ àná
Occasion - I went to an occasion last night
Ìgbéyàwó - Ọ̀la ní ìgbéyàwó wọn
Wedding - Their wedding is tomorrow
Ọdún - Mi ò kì í jáde lọ́jọ́ ọdún
Festive - I don’t go out on festive day
Orin - Mò ń gbọ́ orin
Music - I am listening to music
Olórin - Olórin ni
Musician - He is a musician
Ijó - Ó fẹ́ràn ijó
Dance - He likes dancing
Ìdùnnú - Ìdùnnú wa ò ní di ìbànújẹ́
Happiness - Our happiness will not turn into sadness
Ìbànújẹ - Ìbànújẹ́ pin
Sadness - Sadness is over
Ẹ̀kọ́ - Ẹ̀kọ́ dára púpọ̀
Education - Education is important
Ìdánwò - Mi ò fẹ́ràn ìdánwò
Examination - I don’t like examinations
Ọmọdé - Àwọn Ọmọdé ń ṣeré
Young child - The young children are playing
Eré - Ó fẹ́ràn eré
Play - He likes play
Ǹǹkan - Nǹkan mẹ́ta ni mo fẹ́
Thing - I want three things
Ayé - Ayé ò le
Earth, world, life - Life is not hard